
Akojanu-Ile Igbimo Asofin Ipinle Òyó ti o n soju Ijoba Ibile Atiba, Asofin Gbenga Joseph Oyekola, ti pe Ipe Si Eka Ijoba Ipinle Òyó Lati so Okun Aabo Le Si Ijinigbe Gbowo Se n di Gbon mo-Gbonmo Ni Ilu Òyó ati agbegbe ree.
Nigbati o nse agbekale Aba Ohun, ni Ile Igbimo Asofin Ipinle Òyó lanaa, Asofin Oyekola Kiyėsi akitiyan İjoba Ipinlệ Qyợ lábé Qlólájúló, Gómìnà Seyi Makinde láti pèsè ààbò tỉ ở fokanbalệ fún tonilệ tálejo ni lpinlệ Qyó, tí ó sì ti ń so èso rere.
O so wipe, Egbělégbè owó ni ljoba ti ná látàrí síso ökun àábò lé danin-danin. Lára àwọn igbésè tí ó ti wáyé ni rirà ọkọ àti alúpupů fún igbókè gbòdò àwọn òsisé eléėto ààbò, gbigba òpòlópò òşişé eléèto ààbỏ Ảmộtékůn àti bệębéệ lọ.
Oyekola túnbộ kíyèsi pé pèlú akitiyan ljoba lóri étò ààbò yii síbèsibè àwọn agbésùnmòmí wọnyi kò síwó láti máa gbógun ti àwùjo nipa ijínigbė gbowó, bíó tí ń wáyé láti owộ àwọn Fúlàni òdárán nàà ni ó ń wáyé láti owó àwọn ọmọ “gànfé”.
Adari llé, ní bi ọjó mélòó ken séyin ni àwọn afurasi ajínigbė wo ilé kan ní àgbègbè Jóbèlè ní ilú Qyợ ni bii àgògò kan òru tí wọn sĩ mú iyàwó nígbàti ọkọ jóvó ara rè fùn wọn ki wọn ở lè báa fi iyawo rè sílệ, lėyin èyii ni wọn bèrè fún owó itúsilệ tí kò mọ ni iwộnba léyìn tí wọn gba owó nàà ni wọn tủ arákùnrin náà sílè.
O tun wòyé pé, işèlệ yii ti n di gbọn mộ-gbộn mộ nỉ llú Qyọ àti àgbėgbè rè èyí ti kò fi àyà àwọn olùgbé llú náà balệ tí àtisùn pèlú didi ojú méjèèji kò wộpò mộ. Wọn ní tí ààyè bá gba èkúlú odàn nişe ni nipàn láyà bí ìrá. À ì tíì wà egbò dèkun fún iwà ijinigbé yii tí mú kí iwà náà ó máa pėlėkė sí, pàápàá jùlọ ní ojúná okò àtijó tí ilú Qyó sí ilú Ìbàdàn.
Orişirişi îròyìn ìbànújé ni óún dé sí etígbó wa nipa bí àwọn ènìyàn ibi yii șe ń dá àwọn awakò lónà ní ojú ợnà yìi, tí wọn si ń jíàwọn ènìyàn gbe lọ. Àwọn àgbà bỏ wộn ni àilásọ lórùn pááká ótó àpérò fún orno eríwo.
Pèlú gbogbo akitiyan ljoba lábé idari Qlólájúlò, Gómìnà Seyi Makinde láti ní àwùjo tí ó fi çkản balè, ijinigbé gbowó láti owo àwọn èniyan ibi yii ni ilú Ôyó áti ágbègbè rẻ ti n di erú jeje, eyi ti o ti í mú ikaya sốkè bà gbogbo olügbé ilú Qyó áti ágbégbé rẻ lwà yìí ì gógó đẻ bii pe idúnkókó mộ êtô đá bò yli ti bà đẻ ibi pé eni ti wòn bà ji niyăn rẻ gbe ko tún gbodo tojó sún ágbófinró äyäfi ki wón ở lọ san owo idanile ayi ti awon ajinigbé yii bà béère fün. Ni kétë ti owo yii ba ti di sişan, àwọn eniyan ibi yli ó da awọn ti wón bà ji gbe silè pélú idünkókó pé tí wọn bà jùwe tabi so ohunkóhun fún àgbófinró pipa ni àwọn yió pa irúfé éniyán béè pèlú awon ębi re
Mopë irüfé idünkökó mòni yii ni ko je ki awọn arà ilú ó mod adá orúnlá si nipa fifi awon isèlè ijinigbé yii tö ágböfinro leti. Adari ilé, ododo oro ni pë siwájú ni Gómina ti kë gbájäre töri afintó firi awon agbésünmomi läti apá óke oya si awọn inú igbo ni gbogbo apá ilệ Yorùbá tỉ kò yo ilú Qyó àti àwọn ágbègbè rè silê. Bỏ tilè jé pé àwọn àgbófinró, páápáá júlo ilé isé olópáa ń se takuntakun pělů Ifowosowopó áwọn eléėto ääbó miran láti má jệ ki awọn onisünmomi yii pitù owo wọn ni lpinlệ Qyó, sügbón kin ni ki a ti pe ti awon jandükü abi omo is tá tí àwọn nàà ti jinlệ nínú ijinigbé gbowó láwújo wa
Túnbộ mopé, púpò áwọn omo işộtá wonyi ni won fi ilé ljo lilo ni aláálé bo ojú se isé làábí wọn nigbati ó jé pé gbogbo agbégbé ni ó ti di ile ijo ati ile oti áláálé bayil, eyi ti yiò si máa jệ ibi lbojú fún àwọn onisé ibi wonyi. Yatò sí pé àwọn ilé ijo wonyi jé ibi ibojú fún àwọn onisé ibi, bakannáà ni púpò àwọn ilé ljo, páápáá jūlo àwọn tó wà nỉ àwọn àgboole kääkiri ń şe akóbá fün ėto ilera áwọn olùgbé àgbėgbè tí wọn và wonyi, látári ariwo ilú àti èéfin igbómimü èyi ti ó n se onigbówó fún iwa kikiwà bii àlónilówó gbâ, ifipá bánilópò, ijinigbė ati bé béệ lọ.
O wa gbàràtà pé, ijoba gbóđộ fi kún akitiyan rè lori gbigbé ogun ti awọn ìwà jándůků èyí tí ó ń se onigbộwó fún àwọn ìwà òdárán nlánlá ni lpinlệ Qyó áti ni ilù Qyợ àti àgbègbè rè, ní pátaki jūlo, ki akitiyan Gómina Seyi Makinde lè tún bọ fojù hàn dáadáa.
Gbogbo Ile Fẹnu kò láti rộ Èka àlase láti pase fún:
llé işe eléèto áábò Amộtékün láti tún bo se àfikún àwọn èsó Amộtékún tó wà ní llú Qyo àti àgbègbè rè.
Amúgbálégbè Góminà lóri ètò ààbỏ láti șe àgbátérů ikórajopò àwọn eléèto àábó abélé, àti àwọn ode fún şişe ikúnwó fún àwọn Amộtékün ati eléèto àábò ti ljoba Åpapò lórí gbigbé ogun ti àwọn onisunmomi.
llé işẻ tó í rí si ètò Àșà àti irin àjò ìgbafé pèlú lkúnwý àwọn ágbófinró láti ti àwọn ilé ijo ti kò bả ôfin mu pa láti děnà ikórajopò àwọn onişė ibi láwùjo wa.